Skip to content
Lyric
Dive
Public playlists
My playlists
Search
Sign in
OBT ft. BhadBoi OML
Shoday
Popularity · Low
+
Original
0
0
YouTube
Searching YouTube...
Lyrics
Original
Translation
Bilingual
Oh, baba yẹ, dáhùn s'ọrọ mi
Oh, my maye, ma ma k'ohùn mi
One big transaction, tó ma change story mi
Malaika tó n gbé're, jọ wá gbé'rẹ s'odo mi
Oh, babá ye, dáhùn sọrọ mi (Ob—, Obah)
Oh my maye, ma ma k'ohùn mi (wah dem a say?)
One big transaction, to ma change story mi
Malaika tó n pín'rẹ, jọwọ pín'rẹ d'odọ mi
Wọn ni Naija ṣi ma dùn, but you dey America
E go better la ti n gbó la t'aye Abacha
Owo t'ọmọde bá kọ'rí, á fi jẹ akara
If I see first money, mo ma sá lọ Canada
Oh, baba ye, dáhùn s'ọrọ mi (Shoday, kí lo dé?)
Oh, my maye, ma ma k'ohùn mi (mm)
One big transaction, to ma change story mi
Malaika tó n pín'rẹ, jọwọ pin're d'odo mi (oh, babá yè)
Oh, babá ye, dáhùn s'ọrọ mi (dáhùn s'ọrọ mi)
Oh, my maye, ma ma k'ohùn mi (ma ma k'ohùn mi)
One big transaction, tó ma change story mi (ehn)
Malaika tó n pínrẹ', jọwọ pin're d'odo mi (oh, baba yè)
Ibí e ní gbégbé kò ma gbé, ibè ló ma gbé (ibè ló má gbé)
Ọjà to ni gbégbé kò ma gbé, gbogbo ẹ ló ma gbé (gbogbo ẹ ló ma gbé)
Purple Haze ninu brown rizzler, high me my canister
Oh my maye ye-ye, wa gbé mi trabaye, ye-ye
Ayy, it's going, it's going, olomi kò ní s'oṣi, kò ní s'ofo
They're trolling their father, I'm stoning pẹ'lú kpoli, pẹ'lú coco
Kò sí problem, kò sí yawa, kò sí story, kò sí glory, ọmọ ologo
Ah, dorime fún ọmọ ọpẹ (dorime fún ọmọ ọpẹ)
Ọmọ oro mi wá pẹ (ọmọ oro mi wá pẹ)
Oh, baba ye
Oh, baba ye, dáhùn s'ọrọ mi (dáhùn s'ọrọ mi)
Oh, my maye, ma ma k'ohùn mi (ma ma k'ohùn mi)
One big transaction, tó ma change story mi (ehn)
Malaika tó n pín're, jọ'wọ' pín're d'odo mi
Oh, baba ye
Oh, baba ye, dáhùn s'ọrọ mi (dáhùn, dáhùn, dáhùn; dáhùn s'ọrọ mi)
Oh, my maye, ma ma k'ohùn mi (ma ma k'ohùn mi)
One big transaction, to ma change story mi (ehn)
Malaika tó n gbé'rẹ, jọ wá gbé'rẹ d'odo mi (gbé-gbé'rẹ d'odo mi)