Skip to content

Àṣìṣe Ò Sí

Sola Allyson
Popularity · Low

YouTube

Searching YouTube...

Lyrics

Ibeere po lokan mi Sugbon mo mo poluwa dara Irin ti mo n rin o jin gan Sibe ninu e mo mo poluwa dara Awon ibeere yi nwa nko Idahun yen nibo lati wa Olutoni farahan mi o Lori ibeere to wa lokan mi Ibeere po lokan mi Sugbon mo mo poluwa dara Irin ti mo rin o jin gan Sibe ninu e mo mo poluwa dara Awon ibeere yi nwa nko (Idahun yen da) Idahun yen nibo lati wa Olutoni farahan mi o (mo gboju soke si o) Lori ibeere to wa lokan mi Sugbon mo mo Asise o si loro re Asise o si leto re Asise o si loro re Asise o si leto re Asise o si loro re Asise o si leto re Asise o si loro re Asise o si leto re Igba miran gbo gbo e atie sun ni Sibe ninu e mo mo poluwa dara Ibi ti mo n lo o shi jin gan ni Ito ni mo bere ajo ko san mi Awon ibeere yi nwa nko (awon ibeere yii wa nko lokan mi) Idahun yen nibo lati wa Olutoni farahan mi o Lori ibeere to wa lokan mi Sugbon mo mo Asise o si loro re Asise o si leto re Asise o si loro re Asise o si leto re Asise o si loro re (ibanuje le wa sugbon oo kin sasise) Asise o si leto re (gbogbo oun to fa ibanuje lona mi bami mukuro) Asise o si loro re (shaanu mi oba imole tan imole fun mi) Asise o si leto re Itura a de Iranwo a wa Moni ireti Asise o si o Itura a de (ogbe a san) Iranwo a wa (itura a wa) Moni ireti (ogbe okan ogbe ara a san) Asise o si o Itura a de (womi san lemi) Iranwo a wa (womi san lokan, womi san lara) Moni ireti Asise o si Dariji mi Itura a de (gba mi lowo esu) Iranwo a wa (eyi ti mo ba n le) Moni ireti (eyi ti mo fowo ara mi fa) Asise o si o Sibe sibe mo mo Asise o si loro re (mo mo daju pe asise o si loro re) Asise o si leto re (Olu saanu gbogbo eniyan asise o si) Asise o si loro re (asise o si o) Asise o si leto re Mo gbekele o oju oni ti mi Asise o si loro re (mi o ni jiya gbe maa ni ere to po) Asise o si leto re (maa rin lona to to ninu eto re o) Asise o si loro re (asise o si loro re oluwa o) Asise o si leto re Asise o siii Asise o si loro re (mogba asise o si loro re) Asise o si leto re (oun gbo gbo n sise po fun daa daa ni) Asise o si loro re Asise o si leto re Asise o si loro re Asise o si leto re Asise o si loro re Asise o si leto re