Skip to content

Anu Ni Mo Fe

ADUKE GOLD
Popularity · Low

YouTube

Searching YouTube...

Lyrics

Iwo nikan lo mo ju To pe ju, to funfun ju Iwo nikan lo ri inu to rokan gbogbo eniyan Iwo nikan la o le sigba fun Ta o le binu so, ta o le dalebi Bo to run o lo n sola To n pin ogo fun gbogbo eniyan O se farau laye le Iwo lo tun ran mose ko lo ba Orile ede meji nbe ninu re Aburo laa ma soga egbon Jefta omo ale, o tun mu pada dolu omo Ta a to dete re lojo idajo Ojo anu ni ko foro mi si Ta a to woju re lojo idajo Ojo anu ni o foro mi si Bi mo ba ranti gbolohun yen oo Pemi o saanu fun eniti temi o saanu fun Emi a si sojurere mi seni ti ma sojurere si Ise ma ko anu olorun ni Ise eee ma ko oo anu olorun ni Anu ni mofe Anu ni mo bere Anu ni mofe ooo Baba ise ko lowo Anu ni mofe Anu ni mo bere Anu ni mofe ooo Baba ise ko lowo Jaakobu ni mo feran Esau ni mo korira Taleni to le mu o si iiii Iwo lo daye olorun mi amo o o pin dede o Awon kan gbenu Ile awon kan gbenu Igbo Taleni to le mu o si Awon kan wa omo were bi ibeji ko reni gbe Taleni to le mu o gan Samueli rele Jesse lati lol yanba titun fun isreali Eliabu akobi lo koko jade Tewa tewa ti giga ti giga Samueli ro pe a ti roba oo Baba mi je ko ye wipe mo ko oo Ma woju re ma wo giga re Mo ko Eyan woju olorun wokan Mo ko Eyan le rewa ko ma raanu gba oo Jeh olorun ooo Awon mejeje koja niwaju woli Sibe olorun ko won Anu to sonu laye won Davidi lo ri re Ori ogo nbe ninu igbo oo Ori ogo n toju ori aguntan Bi mo ba ranti gbolohun yen Pemi o saanu fun eniti temi o saanu fun Emi a si sojurere mi seni ti ma sojurere si Ise ma ko ooo Anu olorun ni Ise mako oooo Anu olorun ni Anu ni mofe Anu ni mo bere Anu ni mofe ooo Baba ise ko lowo Anu ni mofe Anu ni mo bere Anu ni mofe o Baba Ise ko lowo Olorun lohun ma gbe o ga O so folorun pe o leni kankan Banu ba de bo ba ranu gba Ibi giga lo pe o ko wa logo re Olorun ni wa fomo sile saye lo O so folorun wipe baba mo ti dagba To ba ranu gba oro re a ka ye logbon Pe ba o ku oo ise o tan Olorun sope ohun ma kole fun oo O da olorun lohun pe o lowo iso Seni to kole fun o teni yen o je nile lori A se ooo pelu ase irorun Anu ni mofe Anu ni mo bere Anu nikan lo le bamise ooo Tori pe ise ko lowo Anu ni mofe Anu ni mo bere Anu ni mofe oo Baba ise ko lowo (Aaaaaanu ni mofe) Anu ni mofe Anu ni mo bere Anu ni mofe o Baby ise ko lowo Anu ni mofe Anu ni mo bere Anu ni mofe o Baba ise ko lowo