Skip to content

Ki Oluwa so Ipade Wa

Popularity · Low

YouTube

Searching YouTube...

Lyrics

Esu ma se mi Omo elomin ni o se Esu ma se mi Omo elomin ni o se Onile orita Omo elomin ni o se Emi o gbero ika senikeni Emi o gbero ika senikeni Oluwa ko so pade wa Emi o gbero ika senikeni Emi o gbero ika senikeni Oluwa ko so pade wa Atawa to n lulu ateyin to n jo ka ma fekun ohun ose ya Atawa to n lulu ateyin to n jo ka ma fekun ohun ose ya Moti layo ninu Jesu Halleluyah Oba mimo lofife ramipada Titi aye lemi oma kaleluya Halleluyah Oba mi olore Mokiyin pupo ka ma fekun ohun ose ya Tunde Ibukun ose ka ma fekun ohun ose ya Oyinbo oni... mi o ka ma fekun ohun ose ya Tunde lawrency mi ka ma fekun ohun ose ya Oko kudi owo ka ma fekun ohun ose ya Amodemaja roloye mi ka ma fekun ohun ose ya Mokiyin pupo ka ma fekun ohun ose ya