Skip to content
Lyric
Dive
Public playlists
My playlists
Search
Sign in
GTA
Seyi Vibez
Popularity · Moderate
+
Original
0
0
Listen
YouTube
1
2
3
0:00 / 0:00
Loading YouTube player...
Lyrics offset
Synced
Lyrics
Original
Translation
Bilingual
Tell the woman 'o ma jere iṣẹ rẹ'
Akaba to dẹ l'awa fi gbera
I don go many places
I don see many faces
Real life GTA
Mo da bi grand theft auto
Gamer!
I don go many places
I don see many faces
Real life GTA
Mo da bi grand theft auto
Automatically, baby
Automatically, baby
Mo maa jẹ'ṣẹ yẹn
Toyin Tomato
Uhn-uhn
Baby mọ pe aye pọ gan-an
I can never joke with this your love
Carry me go, carry me comot
Anything you want, ba mi sọrọ
Uhn-uhn-uhn, no suffocation
I dey go jẹjẹ o, ọmọ Eko
Carry me for yansh, sisi Debo
Oh, Fujiana
Mo ya'wo kọrin ki n to ṣe aṣela
Right now, Ẹmi-Mimọ bale mi
All white dressed, and I wan party
Awọn ọmọ oro n cho, wọn wọ Frank Muller
Mo ta tan sibẹ ki n le gba mulla
Lat'ọmọde mo ti jọba
Lat'ọmọde mo ti jọba, ah
Fujiana, ko ṣe normal
I don go many places
I don see many faces
Real life GTA
Mo da bi grand theft auto
Gamer!
I don go many places
I don see many faces
Real life GTA
Mo da bi grand theft auto
Automatically, baby
Automatically, baby
Mo maa jẹṣẹ yẹn
Toyin Tomato
Tell the woman 'o ma jere iṣẹ rẹ'
Akaba to dẹ l'awa fi gbera
Baba lo maa mọ bo ṣe jẹ-ẹ
Ilahi la n pe, o dẹ ma gbe e wa
Ẹ ran mi niṣẹ, mo dẹ n jẹ ẹ
Akaba to dẹ l'awa fi gbera
Baba lo maa mọ bo ṣe jẹ-ẹ
Ilahi la n pe, o dẹ ma gbe e wa
Tell the woman 'o ma jere iṣẹ rẹ'
Akaba to dẹ l'awa fi gbera (akaba to dẹ l'awa fi gbera)
Baba lo maa mọ bo ṣe jẹ-ẹ (Baba lo maa mọ bo ṣe jẹ-ẹ)
Ilahi la n pe, o dẹ ma gbe e wa (ilahi la n pe, o dẹ ma gbe e wa)
Ẹ ran mi niṣẹ, mo dẹ n jẹ ẹ (ẹ ran mi niṣẹ, mo dẹ n jẹ ẹ)
Akaba to dẹ l'awa fi gbera (akaba to dẹ l'awa fi gbera)
Baba lo maa mọ bo ṣe jẹ-ẹ (Baba lo maa mọ bo ṣe jẹ-ẹ)
Ilahi la n pe, o dẹ ma gbe e wa