Skip to content
Lyric
Dive
Public playlists
My playlists
Search
Sign in
Jerimoyah
Wizka
Popularity · Low
+
Original
0
0
Listen
YouTube
1
2
3
0:00 / 0:00
Loading YouTube player...
Lyrics offset
Synced
Lyrics
Original
Translation
Bilingual
Oh-ohh, ohh-yeah
Wizka, makun sko, ohh
Yeah-yeah-yeah, Jerimoyah l'é
(Train Wavy TK, mix it, baby)
Ohh, ayy-yy
Jerimoyah l'é, Jerimoyah l'èmèjè
Jerimoyah l'émèjè, oh-l'émèjè
Jerimoyah l'émèjè
Ọbá t'òn gb'èdè k'èdè
Ọbá tòh dári sànmón mèjè
Ọbá tiò ma l'áfiwè
É jé á sòh itàn jànmó mèji
L'óbá ló s'ódó wòli
K'òlè d'ólá, k'òlè nìyi
Wòli s'óró f'ákókó, wi pè "òwò nbó wá fún"
Sugbón láálá póju, f'òmó édá Adam
Wòli té siwáju ló
L'òbá s'óró fún ikèji, wì pè "á r'òwò òjijì" (wì pè "á r'òwò òjijì")
L'òbá kò ájè mèji, l'ówó awón jànmó mèji
Wì pè "é wì nté fé si, l'òwuró f'ójó mèjè"
Sugbón ranti ènìkèji
Ọbá mi á má d'árá shá, rárá, kòs'éni bi
T'òbá d'èni, ò lè d'ólá, kò d'òdì fún ikèji
Ọbá mi á má d'árá
Òju áyè
Ò bá gbó nti time sóh, wá mó pè kò s'áláyè
Ò nì ìbì t'èrè pór sunmó, ni ikèji át'ákókó
Wòli má l'òn f'èdè fọh, wì pè "kòsi anybody, tá nkán t'Òluwá wì"
Ákókó l'ólá pó ju, ò s'óró s'ájè pó ju
Ikèjí d'éri ípónju, ò p'òshé ju ájè sọn
Ilahi, Óbá yì, má shèè wò mi
Ábiámọ t'òlójá yì
Mò d'èrò t'òri gáhin, Ilahi
Ọbá mi á má d'árá shá, rárá, kòs'éni bi (ye-ye)
T'òbá d'èni, ò lè d'ólá, kò d'òdì fún ikèji
Ọbá mi á má d'árá shá, rárá, kòs'éni bi
T'òbá d'èni, ò lè d'ólá, kò d'òdì fún ikèji
Ọbá mi á má d'árá shá, rárá, kòs'éni bi
Ò lè d'ólá (Train Wavy TK, mix it, baby)
Kò d'òdì fún ikèji