Skip to content
Lyric
Dive
Public playlists
My playlists
Search
Sign in
London Gist
Oriyomi Kehinde
Popularity · Low
+
Original
0
0
YouTube
Searching YouTube...
Lyrics
Original
Translation
Bilingual
T reign on the mix
Alubarika, alubarika ninu isemi alubarika
Alubarika, alubarika ninu isemi alubarika
Alubarika, alubarika ninu isemi alubarika
Alubarika, alubarika ninu isemi alubarika
Yah robbi, asoromaye asoromaye ose Olohun asoromaye
Asoromaye, asoromaye ose Olohun asoromaye
Oriyomi ero mi lose, ero mi lose Olohunkemi oromi dayo
Ero mi lose, ero mi lose Olohunkemi oromi dayo
Toripe moti so tele, mo sorokan tele ninu orin mi tokoja lo
Wipe moti d'abidjan, mo wolu ghana, mode to go mo moyan tope o
Maa sha Allah
Mowa lame loku, motoro london moka getmany mo ati canada
Ooh obami alase, obami alase
O fase toda si gbolohun mi loromi base
Alubarika, alubarika ninu isemi alubarika
Seri gbogbo ilu toku, awon countries toku momope laipe matun debe
Alubarika, alubarika ninu isemi alubarika
Mo wolu uk mo delu london awon aye kimi
Jummiey entertainment logbemi lati naija de london
Mo bale si gatwick, mo bale si gatwick mofi croydon sebugbe timowa
Serawon tonwa pademi, mo riwon tan gan emi gan lanu
Yes, okanlomo sheffiield o gbera lodo e gan wa bami
Esaari baba gaji ganwa, won wa pademi iyen ni airport
Oh, at'ajoke amodu fatima jummmiey entertainment
Alubarika, alubarika ninu isemi alubarika
Alubarika, alubarika ninu isemi alubarika
Kise africa nikan mo international lomo
Kise africa nikan mo international lomo
Gbogbo agbaye countries toku lama gberede
Kise africa nikan mo international lomo
Gbogbo agbaye countries toku lama gberede
Oriyomi mo wolu london, mosere ni peckam
Lodo angel promotion, lojo ibi e gangan
Bee, atun sere ni woolish, awon ti london peju
Gajbash promotion, baba gaji ni london
Ati dubai entertainment, pelu jummiey entertainment
A gbere denu catford kotodipe awa sile
Mode manchester mori sheradis olufimo manchester
Sheriff adisa salawu olufimo manchester
Baba amina baba oni faruku baba seyifunmi, ola baba fawaz
Baba tojumi nibe, mo lafia mo gbalafe
Ni manchester mori oloore mi, ismaila komolafe
Alase silvergold entertainment, owo baba muhanmmad
Baba amira baba oni qowwiyah
O tojumi ni manchester
Oriyomi moni orekan, ni sheffiield
Egbomi nigeria ko o, ni sheffiield
United kingdom ni, oriyomi uk nimoso, ni sheffiield
Oun l'adesina abdulfatai, ni sheffiield
Ololade okanlomo, ni sheffiield
Okanlomo lawon aye npe o, ni sheffiield
Okanlomo toyayi togbafe, okanlomo togbayi tomoyan
Modupe accommodation ni sheffiield
Ololade adesina mi akanbi, ikeji mi nilu uk eyan ni
Towotowo lofinbami se tenuko
Baba suliya omolabake baba ajoke, faida lajoke timoso
Ola baba jibola ni scotland
Baba abike khadijah lokanlomo
Okanlomo kolohun mayawa, sebawa lanirawa
Ba nk'obafemi omo afuwape, oko oyinbo oba ninu sheffiield
Baba sharon owo baba lil, iwo leyan riliwanu cooler
Bami ki afolabi eyanre laluko, sebawa lanirawa
Alhaji wasiu majek ni london, majekodunmi omo abeokuta
Oko alhaja sekina anike, wuraola mama dodondawa
Mama abdulllahi omo won nibadan
Won setoju mi ni london lojosi
Won tunwa mumi molu kaakiri, won tunwa sagbo mi nomi lowo
Ebanki yemisi omo owoso, godmother fun seki wuraola
Bese funmi lebun loje kinmope
Sebawa lanirawa
Mo ranti teemah nilu london
Everything by teemah abikeade
Kobami ki sofiyatullahi
Oun laburo iburo peckham, oluomo woolish
Miole gbagbe moriamo gangan
Alhaji saka mido ni italo
Oko esther king of empowerment
Ola baba fathia baba tunde
Ife ti eni simi loje kinmope
Sebawa lanirawa
Oba to lana sibi ta o to
Ko tunje loja sibi taofe o
Ona irorun lofi fie modo mi
Loje kole ma bami lofe o
Gbadebo lofi kemi, koni bo lowo mi
Abiodun hassan gbadebo mi o
Eniyan kan soso bi egberun
Koma da ara e beseri towa yen
Yah Robbi loda bose wayen
Suuru loni nigba kosi o
Adua lose si idanwo ri o
O suffer ri koto le deyan
O royin funmi bose poto
Oshi osimo ola lo ku fun e
Igba ti onitan salo nlo lo
Konibaje fun e engineer hassan
Gbadebo baba mmm mi ni
Hassan tofi keni, koni bo lowo mi
Abiodun tofi kemi, koni bo lowo mi
Engineer hassan wo mogba fun e
Torololufe mi tonse temi ni
Alhaja hassan gbadebo mi
Abiodun o ni bawon sise
Oko monsura titilayo mi
Alhaja monsura alashake
Baba muiza baba muiz
Baba mustekimah mmm ni
Hassan tofi kemi, koni bo lowo mi
Olote kan ni hassan bawo
Po kere, o lokere
Oni hassan omo ojo woni
O kere, o lokere
Ore ojo ori ko lagba ejo, kowabikan joko si
Ipo lagba t'everybody gan mo
Toba ni hassan kere stature lonwo
Structure lonwo gbadebo o kere
Elegan kan tun ni hassan o lowo
O ni kiloni
Toba sope hassan o lowo
Toripe ko sakoni, kode segberaga
Gbadebo o kere
Eru to j'owo e lo ni
Gbadebo o kere
Oògbori small body big engine
Gbadebo o kere
Alase hazland builders
Gbadebo o keere
And properties limited
Gbadebo okere
Hazland m builders seb'oshodi lowa Gbadebo o kere
Engineer tonbani kole, gbadebo o kere
Ebami k'alhaji olota, gbadebo o kere
Oun lalaga muslot properties
Gbadebo o kere
Hassan omo won nilu ede, gbadebo o kere
Nilu ede lagbole kusi, gbadebo o kere
O ni kinki mama funky, gbadebo o kere
Sherifa pelu adija, gbadebo o kere
Habibu pelu suliya, gbadebo o kere
Ati halima shadiyah, gbadebo o kere
Alhaji oluwo viber, gbadebo o kere
Pelu otunba longe, gbadebo o kere
Ati eyan e ifa orangutan, gbadebo o kere
Ebanki olalekan sherifdeen, gbadebo o kere
Ola salam record, gbadebo o kere
Asiri ola kan koju base nna
Eni tioni seri taba nbo lasiri
Ina oni tanwo eni to nseranlowo
Koni tanwo eni tonbo asiri
Alhaji prince kolawole qosim alesinloye
Ajagbe ade omo omo olubadan akoko
Houston texas lamerica salomo ngbe
Oko queen hajjia mariam omobolanle
Alase mummy blue kitchen
Food & catering l'america
Onilenla tuntun tako tasi nilu ibadan
Mo debe lojoyen, ajo sadia sini
Olori akagbe kosimu aleshinloye
Kolawole tigoke na kafara toja
Toripe kosaun ina oni tanwo eni to nseranlowo
Koni tanwo eni tonbo asiri
Kolema maribe Olohun abo asiri
Alhaji kolawole abass aleshinloye
Eniyan nie ninu aye Olohun timoyen ni
Lose gbola pamo kotowa pada gbeyo
Tori latijori nigba tomo o rije
Alataarago nigba tomo o rise
Won ro p'ajagbe onila
Opo won ti ro e pin, koni dekun fun e
Gbogboun tonpa e lerin
Ina oni tanwo eni to nseranlowo
Koni tanwo eni tonbo asiri
Asoruko ta somo, ase yio pada romo
Kolawole lomo nje
Opada kolawole
O tun fola e rannmo
Alhaji qosimu mi olawole aleshinloye
Ajagbe baba andulkareem
Eyi tonje akanji
Owo baba ridwan tonse soldier lamerica
Oun lonje akanmu
Baba adetokunbo
Abdulasalam mini
Tonje boladale ayinde okin
Eba nkoloruko mi uncle kehinde akanni
Kolawole aleshinloye ore alhaji olalekan
Sahdullah omo aropoko
Iyen nilu ibadan
Eyan alhaji taoheed mi
Fakunle baba aliyah
Owo baba imran
I.t engineer lamerica
Omowon nilu ibadan, toripe kiisaun
Ina oni tanwo eni to nseranlowo
Koni tanwo eni tonbo asiri
Oriyomi oshodi molo moma gboro eyan kan ni
Ninu alaso mogbo pe eyan kan wa
Tobolohun ke tio ko ola e kere
Hajja habiba ajokeade iyalaje
Oshodi molo moma gboro eyan kan ni
Ninu alaso mogbo pe eyan kan wa
Tobolohun ke tio ko ola e kere
Hajja habiba ajokeade iyalaje
Ajoke po leyan, koma bawon jiyan mo rara
Bere loshodi, oma gburo eyan kan nla
Ajoke o niyi, o ju t'oba ibikan lo
Awon tonri e tonfi e je iyalaje
Lajewole market araromi oshodi wa
Won mo eni toye nonse fie je iyalaje
Aye nferan e, Olohun mapa karamo
Hajja abiba koma folapitan lailai
Ajoke ade mori e moko eyanre
Oshodi molo moma gboro eyan kan ni
Ninu alaso mogbo pe eyan kan wa
Tobolohun ke tio ko ola e kere
Hajja habiba ajokeade iyalaje