Skip to content
Lyric
Dive
Public playlists
My playlists
Search
Sign in
Rybeena Go Harder (Official Audio)
Rybeena
Popularity · Low
+
Original
0
0
YouTube
Searching YouTube...
Lyrics
Original
Translation
Bilingual
(Bobo Rybeena yẹn sẹh)
(Rybeena lonpè ẹ ni abi Sabina?)
(Nlike ẹ rárá, kotiẹ fine, ẹnu ẹ tunwá gun)
(Ẹshá l'ọdun mèji t'ẹlo, kẹ ko'gbá n'lè)
(Tori gbogbo yin, ẹn ṣh'olorin)
(It's Jay Fred, The Beat Wizard)
Ayy-ah
Itákun, itákun toni k'èmi má goke
Iyana ohun gbèmi dèbẹ, jábọ
Itákun, itákun toni pè k'èmi má goke
Iyana ohun tèrè mi, wọn l'oni jábọ, oh-ah
We go harder, bad man can't give up
Only mama no love me with condition
Tinbá ranti ngbá n'lowo, o mán kámi n'ṣhàn, uh-uh
So, no time, èbi o lè pá mi mọ
Tinbá ti ri maga t'omá l'ari mọ, 'ṣhèè ninu mi má dun bi k'áṣá ti ri kàn, uh (gbè wa, gbè wa)
Dákun, k'ámá ṣhèè l'ásàn, oje mi ti jẹyá wọn
Olori o jọ rá wọn, biti filá kọ
Okay, mofi cana pẹlu Backii wèrá wọn, ko ṣháti jọrá wọn
Tinbá ti mu'gbo mi, moti dè igbágbọ
Yè, èmi Obama
David in the midst of Goliath
Adewale, ṣh'omọ pè o para
Bomb everywhere like Osama
O l'árá, para-para
Èyàn mi ni Shehu Bulala
Stealing every show like kidnapper
You dey find money, oun pà data, gbà sapa
Ayy, I dey follow you dey bomb, you carry money, you run
Shey because I still dey scut for your place, you come dey use matter dey puff?
Ọdọ mummy mi mo lọ, ngbá tóh lè wá, tiko sibi t'ámá lọ
Sugbọn ọrọ kàn ni mo básọ, mo sọh fun pè "you go meet me for the top" (mtcheew)
We go harder, bad man can't give up
Only mama no love me with condition
Tinbá ranti ngbá n'lowo, o mán kámi n'ṣhàn, uh-uh
So, no time, èbi o lè pá mi mọ
Tinbá ti ri maga t'omá l'ari mọ, 'ṣhèè ninu mi má dun bi k'áṣá ti ri kàn, uh (gbè wa, gbè wa)
Dákun, k'ámá ṣhèè l'ásàn, oje mi ti jẹyá wọn
Olori o jọ rá wọn, biti filá kọ
Okay, mofi cana pẹlu Backii wèrá wọn, ko ṣháti jọrá wọn
Tinbá ti mu'gbo mi, moti dè igbágbọ
Yè, èmi Obama
David in the midst of Goliath
Adewale, ṣh'omọ pè o para
Bomb everywhere like Osama
O l'árá, para-para
Èyàn mi ni Shehu Bulala
Stealing every show like kidnapper
You dey find money, oun pà data, gbà sapa
Dákun, k'ámá ṣhèè l'ásàn, oje mi ti jẹyá wọn
Olori o jọ rá wọn, biti filá kọ
Yè, mofi cana pẹlu Backii wèrá wọn, ko ṣháti jọrá wọn
Tinbá ti mu'gbo mi, moti dè igbágbọ