Skip to content

Iye

Sola Allyson
Popularity · Low

YouTube

Searching YouTube...

Lyrics

Iye a wa Eni to ni iye lodo, a pin temi kan mi o Iye a wa Iye a wa Eni to ni iye lodo, a pin temi kan mi o Iye a wa Iye de Eni to ni iye lodo, O pin temi kan mi o Iye de Iye de Eni to ni iye lodo, O pin temi kan mi o Iye de O wa ooo, O wa O de ooo, O de O wa ooo, O wa O de ooo, O de Aanu de Alaanu f'aanu s'aanu, O mu temi ko mi Aanu de Aanu de Alaanu f'aanu s'aanu, O mu temi ko mi Aanu de O de ooo, O de Isegun wa Olusegun, Ajasegun, O gbe temi ko mi o Isegun wa Isegun de Olusegun, Ajasegun, O gbe temi ko mi o Isegun de O wa ooo; O wa, O de ooo; O de Iye a wa Iye de Eni to ni iye lodo, O pin temi ko mi o Iye de