Ogba Kan Be Loke Orun (Hymn 783)
Popularity · Low
YouTube
Searching YouTube...
Lyrics
OGBA kan mbe l'oke Orun
Ogba Eden ni
Gbo bi awon Maleka ti nyo
Ayo nla nla
Gbo bi ipe na ti dun
Ipe Halleluya
OGBA kan mbe l'oke Orun
Ogba Eden ni
Ogba Eden ni
Gbo bi awon
Gbo bi awon Maleka ti nyo
Ayo nla nla
Gbo bi ipe na ti dun
Gbo bi ipe na ti dun
Ipe Halleluya
Washed in the blood
My soul made new
Jesus has opened the way
No more sorrow
No more pain
Only his glory
O nke kan kan lohun rara
Ipe Halleluya
Ipe Halleluya
OGBA kan mbe l'oke Orun
Ogba Eden ni
Gbo bi awon Maleka ti nyo
Ayo nla nla
Gbo bi ipe na ti dun
Ipe Halleluya