Skip to content
Lyric
Dive
Public playlists
My playlists
Search
Sign in
Realize
Rybeena
Popularity · Low
+
Original
0
0
YouTube
Searching YouTube...
Lyrics
Original
Translation
Bilingual
(Xcuse me, please me)
(Damn)
Omotena just realize (ewe), your limit na sky (ewe)
Girl, your beauty na álèlè, I'm lucky for life
E be once wey I sight, and I catch my fish, mòfi jẹ amala sky
And I go share testimony, 'cause I been dey wait too long to deserve your type
Miò ṣ'èrè, jámi, b'òjẹ irọ ni, my bèbè
B'ọlẹ l'òri matter yen (kò kàn mi)
Me and you, we die here (Alari)
'Cause I get comma, no mean make you full stop, kòyẹ k'òmá lọ báyẹn, ahn
It's how we do the alignment
She understood the assignment
Show me your boundary, I go show you my boundary, miò dẹ ni kọjá ibẹ
Be'-Better jòkò sibẹ yẹn, ibò ni bábá ẹ nlọ? (Bábá ẹ nlọ?)
Ẹlẹyẹlẹ, iwọ ni má bá ẹ lọ
Málọ f'igò gẹ'ri ẹ, ibò ni barber ẹ lọ?
Oh, á'lè má bá báyi lọ
Iyáwò mi, ṣ'òdá tò rò mi pin?
Oyeni ku, Oginni ku
Ọmọ buruku, májẹ kin bá báyi ku
Ò fimi silẹ tàn, mò wá nfá kanaku
Yè, and I go share testimony, arabanko
Mòtun mọ Ájigbò ni, ah
Miò ṣ'èrè (miò ṣ'èrè ò), bọ gbògbò pátá ẹ, my bèbè
B'ọlẹ l'òri matter yen (kò kàn mi)
Me and you, we die here (Alari)
'Cause I get comma, no mean make you full stop, kòyẹ k'òmá lọ báyẹn, ahn
It's how we do the alignment
She understood the assignment
Show me your boundary, I go show you my boundary, miò dẹ ni kọjá ibẹ
B'ọlẹ l'òri matter yen (kò kàn mi)
Me and you, we die here (Alari)
'Cause I get comma, no mean make you full stop, kòyẹ k'òmá lọ báyẹn, ahn
It's how we do the alignment (it's how we do the alignment)
She understood the assignment (she understood the assignment)
Show me your boundary, I go show you my boundary, miò dẹ ni kọjá ibẹ
I-I-Iyáwò mi, ṣ'òdá tò rò mi pin?
Oyeni ku, Oginni ku
Ọmọ buruku, májẹ kin bá báyi ku
Ò fimi silẹ tàn, mò wá nfá kanaku
(Coz-Coz-Cozmicaudio)