Skip to content
Lyric
Dive
Public playlists
My playlists
Search
Sign in
Eni Jesu We
King Sunny Adé
Popularity · Low
+
🇳🇬 Hausa · Original
0
0
YouTube
Searching YouTube...
Lyrics
Original
Translation
Bilingual
Wan l'akaka
Wan l'akaka
Wan l'akaka
Wan l'akaka
Iku Jésù
Iku Jésù lórí mi ko ma ṣe ja s'asan
Wan l'akaka
Wan l'akaka
Wan l'akaka
Wan l'akaka
Iku Jésù
Iku Jésù lórí mi ko ma ṣe ja s'asan
Ko f'okun wẹ'ri o
Ko tun f'ọsa wẹ'sẹ
Ko f'okun wẹ'ri o
Ko tun f'ọsa wẹ'sẹ
Ẹni Jésù wẹ
Ẹni Jésù wẹ
Lo mọ t'akan t'ara
Ko f'okun wẹ'ri o
Ko tun f'ọsa wẹ'sẹ
Ko f'okun wẹ'ri o
Ko tun f'ọsa wẹ'sẹ
Ẹni Jésù wẹ
Ẹni Jésù wẹ
Lo mọ t'akan t'ara
Ẹni Jésù wẹ
Lo mọ t'akan t'ara
Ẹjẹ Jésù
Lo mọ t'akan t'ara
Ẹni Jésù wẹ
Lo mọ t'akan t'ara
Wẹ mi o jare
Lo mọ t'akan t'ara
Ma wẹ ninu yẹrẹ tan r'agutan
Lo mọ t'akan t'ara
Ẹni Jésù wẹ
Lo mọ t'akan t'ara
Ẹni Jésù bá wẹ
Lo mọ t'akan t'ara
Ẹni Jésù wẹ
Lo mọ t'akan t'ara
Iwa mimọ ni n dani ki a mọ
Lo mọ t'akan t'ara
Kan wù wá tó tọ lo yẹ
Lo mọ t'akan t'ara
Tori
Ẹni Jésù wẹ
Lo mọ t'akan t'ara