Skip to content
Lyric
Dive
Public playlists
My playlists
Search
Sign in
BLOOD OF THE LAMB
Barry Jhay
Popularity · Moderate
+
Original
0
0
Listen
YouTube
1
2
3
0:00 / 0:00
Loading YouTube player...
Lyrics offset
Synced
Lyrics
Original
Translation
Bilingual
(V-V-V-V Sticks)
Ijẹtá, 'ṣèni mò kun lẹ, mòfẹ bá Ọlọhun s'ọrọ, miò mọ òhun ti mò fẹ sọ (miò mọ òhun ti mò fẹ sọ)
Bimò ṣè n ri mu, má jẹn mu bọ, Èlèduwá (Èlèduwá)
Ṣá má ṣọmi lọ (Ṣá má ṣọmi lọ)
Baba, one grace yẹn ni, that one transaction
E go change my life for good, oh (e go change my life for good)
Igbágbọ mi sọpá wáidu, ò lè gàn, ò lè ku
Ápátá, tákọ lè-lèti ilè ò lè wò, Iwọ ṣá l'ágbárá
T'òbá di gbè-gbè gbè, You steady come through for me
Áyè ò fẹ ká r'ẹru, ká sọ, áyé ò fẹ ká palash (fẹ ká r'ẹru, ká sọ, áyé ò fẹ ká palash, kalas)
Òhun t'ọmọ èniyàn ò mọ lò pọr ju
B'Ọbá mi bá dè, á dábi wọ l'òmọ ṣèju ('mọ ṣèju)
Ayy, Ọbá iyè, Áṣẹgun iyè, ayy
Iyin át'ògò áti ágbárá, fun ọdọ águntàn nà
Ọbá iyè, Áṣẹgun iyè, ayy-ah
Iyin át'ògò áti ágbárá, fun ọdọ águntàn nà
Ṣèbi iwọ l'ápáṣẹ, t'òn p'áṣẹ
L'òri iṣẹ mi, p'áṣẹ ọtun
N'ilè áyè mi, p'áṣẹ árá ò
Inu ilè mi, p'áṣẹ ò
Ṣèbi mò gb'òju lè, ayy
Ṣèbi mò gb'ọkàn mi lè Ọ
Ki Baba mi f'iyá gbọ òrukọ, áti kọ ọrọ rẹ, titi lái (titi lái)
Ápátá, tákọ lè-lèti ilè ò lè wò, Iwọ ṣá l'ágbárá
T'òbá di gbè-gbè gbè, You steady come through for me
Áyè ò fẹ ká r'ẹru, ká sọ, áyé ò fẹ ká palash, yè (fẹ ká r'ẹru, ká sọ, áyé ò fẹ ká palash, kalas, yè)

(Sunshine)