Skip to content
Lyric
Dive
Public playlists
My playlists
Search
Sign in
Omo Ologo
Zlatan
Popularity · Low
+
Original
0
0
Listen
YouTube
1
2
3
0:00 / 0:00
Loading YouTube player...
Lyrics offset
Synced
Lyrics
Original
Translation
Bilingual
Chechdaproducer (Chechdaproducer)
So
Uh, 'til the second coming of Jesus Christ, I go dey give them
Mù t'ajéro from Monday to Friday, j'ayé ní weekend
I no need up to 16 bars to prove that I am wicked
And, I bet y'all can testify that this young nigga is gifted
Ó yá wọn lẹ'nu bí mó ṣé ńtana tosh 17 to 19
"Best New Act," AFRIMA, l'aba gb'orí wo quarantine
Lockdown fẹ run wá down, l'aba faríga, f'arakí
Kí ló mà gain tin bà fall?
T'ẹbá rí ọta mí, ẹ bámí bi
Kúròńbẹ, lamba yapa, Ọlọhun ń gbọ', walahi-talahi (walahi-talahi)
God dey bless me too much, me, I no deny (me, I no deny)
And that's why they all chasing when I'm driving by (skrr-skrr)
I pray make my Samson no ever meet Delilah
Say, symbol of hope, for their eye, e be like soap
Wọn fẹ kín má f'aya wọ bi crocodile, aṣọ Lacoste
Ó wá l'ara mí, o kùn sẹ, o tún ṣẹ dànù
Fún ẹyín tẹ komijẹ, tẹ ń gbọn mí mù, ẹ ní rì'dààmú
Kúròńbẹ, ọmọ trenches nínú Lamborghini
VVS lọ'run, j'ayé Santorini
Aṣọ Gucci, ṣòkòtò Amiri
Tó bá ṣẹlẹ̀, wá mọ pé ẹṣá ní Richard Millie
Yea, ọmọ ológo, t'óbá tí rímí, o r'ọmọ ológo
Uh, ọmọ ológo, t'óbá tí rímí, o r'ọmọ ológo
Ọmọ ológo, t'óbá tí rímí, o r'ọmọ ológo
Uh, ọmọ ológo, t'óbá tí rímí, o r'ọmọ ológo
Kúròńbẹ sẹ
Stack the money up, stack the money up, ọwọ lo ṣé ìgbòrò (kí ló wí?)
Ra'lé fún mummy, ra fún daddy, májẹ k'owó s'ọjoró (kí ló sọ?)
Te'pa mo'ṣẹ, ẹni mà gá, o dí dandan, ẹsẹ àá gùn (jẹ ọ mọ)
Ó mà ṣíṣ ẹ, o mà làágùn (jẹ ọ mọ)
Ó dẹ le sọ àágùn díí ìgbádùn
E no matter how the background dey be (ehn?)
Ó le dí Arabanbi (ehn?) Ó le sọ "bye-bye" sí garri (sí garri)
All man for himself, ojú láárí
B'ọrọ yí ṣe ń bà ẹ wí, bẹẹ náà lo ń bàmí wí (kí ló sọ?)
Ọmọ trenches nínú Lamborghini (Lambor)
VVS lọ'run, j'ayé Santorini (gbé fún wo)
Aṣọ Gucci, ṣòkòtò Amiri
Tó bá ṣẹlẹ̀, wá mọ pé ẹṣá ní Richard Millie
Ẹṣá
Ọmọ ológo, t'óbá tí rímí, o r'ọmọ ológo
Uh, ọmọ ológo, t'óbá tí rímí, o r'ọmọ ológo
Ọmọ ológo, t'óbá tí rímí, o r'ọmọ ológo
Uh, ọmọ ológo, t'óbá tí rímí, o r'ọmọ ológo
Kúròńbẹ sẹ
Stack the money up, stack the money up, ọwọ lo ṣé ìgbòrò (o wọnú ògo)
Ra'lé fún mummy, ra fún daddy, májẹ k'owó s'ọjoró (well, well)
Te'pa mo'ṣẹ, ẹni mà gá, o dí dandan, ẹsẹ àá gùn
Ó mà ṣíṣ ẹ, o mà làágùn
Ó dẹ le sọ àágùn díí ìgbádùn
So