Skip to content

Mo Wa Lati J'osin

EmmaOMG
Popularity · Low

Listen

YouTube

0:00 / 0:00
Loading YouTube player...
Lyrics offset
Synced

Lyrics

Oh my God! (ìbèrè orin) ìmólè ayé Ósòkalè nú òkùnkùn Sí ojú mi kîn rí o ìfé tó'mu Kí okàn mi ma júbà rè ìrètí fún ayé pèlú'e (ÈGBÈ) Mowá lati jósìn Mowá lati teríba Mowá lati so wípé ìwo l'olorun mi L'àpapò ìwo lótósí L'àpapò ìwo leni're L'àpapò ìyanu lojé sími Oba ayérayé Tówà níbi gíga Nínú ògo lókè òrun Ófi ìrèlè wá sínú ayé tí odá Nítorí ìfé od'aláìní (ÈGBÈ) Mowá lati jósìn Mowá lati teríba Mowá lati so wípé ìwo l'olorun mi L'àpapò ìwo lótósí L'àpapò ìwo leni ire L'àpapò ìyanu lojé sími (ÈGBÈ) Mowá lati jósìn Mowá lati teríba Mowá lati so wípé ìwo l'olorun mi L'àpapò ìwo lótósí L'àpapò ìwo leni ire L'àpapò ìyanu lojé sími Nkò lèmò iye tójé Láti r'èsè mi lórí àgbélèbú Nkò lèmò iye tójé Láti rí èsè mi lórí àgbélèbú Nkò lèmò iye tójé Láti rí èsè mi lórí àgbélèbú (i would never know How much it cost to see my sin) (ÈGBÈ) Mowá lati jósìn Mowá lati teríba Mowá lati so wípé ìwo l'olorun mi L'àpapò ìwo lótósí L'àpapò ìwo leni ire L'àpapò ìyanu lojé sími Mowá lati jósìn Mowá lati teríba Mowá lati so wípé ìwo l'olorun mi L'àpapò ìwo lótósí L'àpapò ìwo leni ire L'àpapò ìyanu lojé sími (ìparí orin) Olorun tó dà àwon òkè ìgbanì Èyin ni mofi Opé mi fún