Skip to content
Lyric
Dive
Public playlists
My playlists
Search
Sign in
Oversability
BhadBoi OML
Popularity · Moderate
+
Original
0
0
Listen
YouTube
1
2
3
0:00 / 0:00
Loading YouTube player...
Lyrics offset
Synced
Lyrics
Original
Translation
Bilingual
(Jessus)
As at now, mòn temperamental (temperamental)
Kọ Apala pẹlu vocabulary (báámi)
Haruna Ishola no do reach this one (báámi)
Musiliu Ishola no do pass this one
Ònilu mi, bámi kò'gi lè ilu
Iyá iyáwò rẹ ò ku ni ṣẹ'yun
Rosco grandma rẹ ò ku ni sálọ
(Na producer you be, you no be God oh)
Na we dey sing, ọmọ, na we dey fò (na we dey fò)
Áwá lá l'Eko, ọmọ, iwin lò ni'gbò (iwin lò ni'gbò)
Ọbá Dubai ti sọ pè "k'ámá mu'gbò" (k'ámá mu'gbò)
Kòku s'ọmọ nà ti yò j'ọṣẹ (kòku s'ọmọ nà ti yò j'ọṣẹ)
Yè, na we dey sing, ọmọ, na we dey fò (na we dey fò)
Áwá lá l'Eko, ọmọ, iwin lò ni'gbò (iwin lò ni'gbò)
Ọbá Dubai ti sọ pè "k'ámá mu'gbò" (k'ámá mu'gbò)
Kòku s'ọmọ nà ti yò j'ọṣẹ (kòku s'ọmọ nà ti yò j'ọṣẹ)
Oversability wan kill me (ayy)
Versatility wan wound me (ayy)
Balenciaga l'ẹsẹ mi (ayy)
Richard Mille l'ọwọ mi (ayy)
Mòti mọ pè Naija ṣimá dun (ayy)
K'Ọlọhun májẹ mọ iyá (ayy)
K'Ọlọhun májẹ á j'ẹbá lọ school (ayy)
Ọmọ better, Naija ṣimá dun (ayy)
Oversability wan kill me (ayy)
Versatility wan wound me (ayy)
Balenciaga l'ẹsẹ mi (ayy)
Richard Mille l'ọwọ mi (ayy)
Mòti mọ pè Naija ṣimá dun (ayy)
K'Ọlọhun májẹ mọ iyá (ayy)
K'Ọlọhun májẹ á j'ẹbá lọ school (ayy)
Ọmọ better, Naija ṣimá dun (ayy)
If life no fair, ẹlò Calamine lotion
Heart of man is deeper than ocean
Emeka, ẹ má-má já mọ ò
Odumodu pink, Odumodu black
Òṣè ọkọ Alimọtu, ọkọ Sadia
Ò l'òwò, ò fun wá l'idea (fun wá l'idea)
E don tey, e don tey, man, I've heard you enough
Ki'ku pá ẹ, iwọ pẹlu idea ẹ