Skip to content
Lyric
Dive
Public playlists
My playlists
Search
Sign in
The Small People's Anthem
Beautiful Nubia and the Roots Renaissance Band
Popularity · Moderate
+
Original
0
0
Listen
YouTube
1
2
3
0:00 / 0:00
Loading YouTube player...
Lyrics offset
Synced
Lyrics
Original
Translation
Bilingual
Oro aye soro o, oro aye soro, oro aye soro
Oro aye ma le o, oro aye male ko ma ye wa o
Oro aye gb'ege o, oro aye gb'ege, oro aye gb'ege
Oro aye soro o, oro aye soro ko ma ye wa o
Awon kan le je, awon kan o ri, awon kan nwo'so asiko
Awon kan nsun s'abe 'gada', awon kan nto 'le jo bi isu
Awon kan nj'oba, awon kan ns'eru,
Awon kan nse bi Olodumare
Omode oojo ns'alaisi, awon kan s'aye d'awa-ma-lo
Awon kan ns'odun, awon kan nsun'kun,
Awon kan nwo'ju Olodumare
Eniyan rere won 'i pe lo, eni buruku won npe ni'le o

Oro aye soro ko ma ye wa o
Oro aye soro ko ma ye wa o
Oro aye soro ko ma ye wa o
Oro aye soro ko ma ye wa o
Oro aye soro ko ma ye wa o
Oro aye soro ko ma ye wa o