Skip to content

Talebale

jay mikee
Popularity · Low

Listen

YouTube

0:00 / 0:00
Loading YouTube player...
Lyrics offset
Synced

Lyrics

A je bi omode ti iya re ran lo s'oja ... Ah ah ah ah ah ah Oja ile aye lati ra, lati ta ... Ah ah ah ah ah ah Sugbon ti ile ba bere si ni su Ti okunkun ba bo 'le Ti onikaluku ba pale oja mo Ma je ki n gbagbe lati ko'ri si'le Jesu o jowo o ma ma je n kuna Ki n ma ba segbe lo se ku fun mi Jesu o jowo o ma ma je n sina Ki n ma ba segbe lo se ku fun mi Nigba t'ale ba le, t'oja aye tu Je ki n r'oko re ba rele Nigba t'ale ba le, t'oja aye tu Je ki n r'oko re ba rele Ijoba orun da bi awon wundia mewa ... Ah ah ah ah ah ah ah Ti won mu fitila won lo pade oko iyawo ... Ah ah ah ah ah ah ah Eledumare ma ma je ki n di alaigbon Fun mi ni ogbon bi awon wundia ologbon Kolobo mi ree o, ro kun pelu ororo Re Ki n fi duro de o Jesu o jowo o ma ma je n kuna Ki n ma ba segbe lo se ku fun mi Jesu o jowo o ma ma je n sina Ki n ma ba segbe lo se ku fun mi Nigba t'ale ba le, t'oja aye tu Je ki n r'oko re ba rele Nigba t'ale ba le, t'oja aye tu Je ki n r'oko re ba rele Mu mi dele o o, mu mi dele