Skip to content

Evergreen Yoruba Songs of Praise 2

EmmaOMG
Popularity · Low

Listen

YouTube

0:00 / 0:00
Loading YouTube player...
Lyrics offset
Synced

Lyrics

Ope ye o o Baba Ope ye o o Omo Ope ye o o Baba Ope ye o o Omo Eledumare a s'ore kari aye O s'ore f'Oba o tun se t'ijoye l'oto Ko ma gbagbe emi omo re rara Ope ye o o Baba (REPEAT) Opelope re (2ce) Aye i ba yeye mi Opelope re... hallelujah (REPEAT) Titi laelae iwo l'Oba Titi ayeraye iwo l'Oba o Niwon igba ti aye yoo ma wa Jesu Kristi iwo l'Oba o (REPEAT) Emi yoo ma yin o Emi yoo ma gbe o ga Iwo sha ma s'atileyin mi Emi o ma gbe o ga (REPEAT 2ce) Mo ki o wipe o se Olorun eleda mi o Mo ki o wipe o se o Olorun gbogbo aye... emi ki o(REPEAT) Iwa laye mi loni E e maa i se mi mo o se mi A mo tori mo r'anu gba lowo Baba o Mo wa f'emi imoore han Mo ki o wipe o se Olorun eleda mi o Mo ki o wipe o se o Olorun gbogbo aye Oloore mi o se o Olurapada o seun Eniyan i ba maa yin Jesu Fun'se rere at'iyanu re (REPEAT) Oluwa, Oluwa wa (2ce) Oruko re ti niyin to (REPEAT) Okan ni emi ati Baba mi jasi (2ce) Jesu n be pelu mi O duro ti mi gboin-gboin Ajinde ati iye Baba n be pelu mi Okan ni emi ati Baba mi jasi (2ce) Jesu n be pelu mi O duro ti mi gboin-gboin Ajinde ati iye O duro ti mi o Alagbara l'Olorun mi Alagbara ni Jesu mi o To ba ti soro bee naa lo n ri Alagbara l'Olorun mi (REPEAT) Call: So f'oro re jafara.Resp: Ko f'oro mi jafara (4ce) Call: Oloore ni Baba o.Resp: Oloore ni Baba to dami (4ce) Call: Jesu olomi iye re o.Resp: Omi iye, iye, iye re o omi iye Call: Olorun Babalola olomi iye re O.Resp: Omi iye, iye, iye re o omi iye Call: Jesu Kristi olomi iye re o.Resp: Omi iye, iye, iye re o omi iye Call: Oba awon oba olomi iye re o. Resp: Omi iye, iye, iye re o omi iye Call: Jesu olomi iye re o.Resp: Omi iye, iye, iye re o omi iye Call: Hallelujah, hallelujah (2ce).hallelujah Resp: Hallelujah...(24ce)