Skip to content
Lyric
Dive
Public playlists
My playlists
Search
Sign in
Ijoba
Kizz Daniel
,
Naira Marley
Popularity · Low
+
Original
0
0
Listen
YouTube
1
2
3
0:00 / 0:00
Loading YouTube player...
Lyrics offset
Synced
Lyrics
Original
Translation
Bilingual
Anumanuma, yea
Wọn fẹ f'owo mi ṣe Italawa o (Italawa o)
(Manyado!)
Vado, Naira
Ti-, ti mo ti gba ijọba ('ba)
Arọbafin l'ọba n pa (lọba n pa)
Tani o fẹ teri ba?
Ka dọbale fun irara o sọ pe ka ma ga (ka ma ga)
Wọn ni oju ẹ lọ, o l'ọdun kan pere (pere)
O sure po ma ni iru ẹ nile (nile)
To ba jẹ emi ni iwọ, mo ma gba fun
Ọga lọga o ma jẹ, ani o gbe fun (gbe fun)
Family first, money next
Smoke weed, fuck bitches
Get money, invest in business
Fake niggas impressing bitches
Ṣo gbọ?
To ba lowo, ko tọju ẹbi (Anumanuma)
Tọju ara, ko si tọju ara ẹ (uhn-uhn)
Ma fi ṣeṣekuṣe
T'owo ba pọ, ko ya fi nnkan mulẹ (mulẹ)
"The boy is good," apa lo n jẹ bẹẹ
Wọn ni ko niṣo, pe wọn lẹnu nibẹ (nibẹ)
Irọ ni, wọn kan fẹ da si'lẹ
T'ọn ba dalẹ, wọn ma fi ẹ si'lẹ
Hello, fi ẹ si'lẹ
T'ọn ba dalẹ, wọn ma fi ẹ si'lẹ
Awọn l'ọn lẹnu wọn, k'ọn maa ro'jọ lọ, awa ta ti gba ijọba (ta ti gba ijọba)
People wey fuck with me, dem dey fuck with me heavy, no be for money, ah
Pressure them! Make them see the passion, make them see hungry man
Anger them! Baba who go God don bless, nobody fit touch am
Uh, dayanmọ ju owo lọ, but olowo laye mọ (olowo laye mọ)
Ka wa ma r'owo na, Lọla Anọbi Muhammo (Anọbi Muhammo)
Ki n ma wọ Uber mo (Uber mọ)
Ki n ma d'olowo ana (olowo ana)
Today I'm outside, my Lord, ki n ma ma ku sọna (ki n ma ma ku sọna)
Ki n ma ma ku sọna, ki n ma ma ku sọna (ku sọna)
Ki n wọ Al-Jannah, ninu Al-Jannah (Al-Jannah)
"Saafu deede, my friend, lemọmu n bọ" (lemọmu n bọ)
"Ọga Ade, show your working, jọọ
I'm done with talk" (I'm done with talk)
Awọn l'ọn lẹnu wọn, k'ọn maa ro'jọ lọ, awa ta ti gba ijọba (ta ti gba ijọba)
People wey fuck with me, dem dey fuck with me heavy, no be for money, ah
Pressure them! Make them see the passion, make them see hungry man
Anger them! Baba who go God don bless, nobody fit touch am
(Manyado!)