Skip to content
Lyric
Dive
Public playlists
My playlists
Search
Sign in
Fuji Fusion
K1 De Ultimate
,
Bella Shmurda
Popularity · Low
+
Original
0
0
Listen
YouTube
1
2
3
0:00 / 0:00
Loading YouTube player...
Lyrics offset
Synced
Lyrics
Original
Translation
Bilingual
(Ẹ ṣe dádá, ẹ má ṣè iká ò)
(Èni ṣá l'ári, ọrẹ wá-)
(Èni ṣá l'ári, ọrẹ wá, ẹ jijò Fuji gàn)
(Ẹ ṣe dádá, ẹ má ṣè iká)
(Èni ṣá l'ári, ọrẹ wá, kò ṣ'ẹni tò mọ ọlá ò)
(Yes)
Mò ni "What's up, ṣ'òlè b'oṣọ?"
Ọmọ gidi, ọmọ professor
Ọmọ t'ọn sọ, kilọ tun fẹ sọh?
N'igbòrò, ọrọ wá l'ọn sọh (l'ọn sọh)
One puff, one kush
Small colo, you don dey run touch (small colo, you don dey run touch)
The way you dance, ò gb'ọkọ ọlọkọ
Lock up, one touch, baby, what's up?
Kilimanjaro
Má pé mi ti kòbá ti já'wò
Kilimanja-ja-ja-ja, ja-ja, ja-ja-ja (oh-oh)
(Ẹ ṣe dádá, ẹ má ṣè iká ò)
(Èni ṣá l'ári, ọrẹ wá, kò ṣ'ẹni tò mọ ọlá ò)
(Át'ágbá, àt'ọmọdè, ṣèbi Ọlọhun l'òlè kòwá yọ)
Òyá, tell me what you see
My brother, tell me what you see, yeah
(Át'ágbá, àt'ọmọdè, ṣèbi Ọlọhun l'òlè kòwá yọ)
Òyá, tell me what you see
Tell me what you see
(Át'ágbá, àt'ọmọdè, ṣèbi Ọlọhun l'òlè kòwá yọ)
Oh-oh (oh-oh)
Uhn-uhn-uhn, yeah, yeah-yeah, eh
Young Alhaji, Dangbana, mòti d'ágbálágbi (mòti d'ágbálágbi)
T'ẹri bá, t'òbá ri
Fine boy Bella, young Alhaji (young Alhaji)

Uhn-uhn-uhn, yeah, yeah-yeah
Wetin concern me? Validation (gbè fun)
President for my nation (gbè fun)
Ọmọ burúkú change formation (gbè fun)
Ah, say panpa-ran-panpan
The matter don cast, ò di yáwá (ò di yáwá)
Panpa-ran-panpan